Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn àlùfáà gbé àpótí ẹ̀ri ti májẹ̀mú Olúwa wá sí ipò rẹ̀, sí ibi inú lọ́hùn ún ilé Olúwa, ibi mímọ́ jùlọ, wọ́n gbé e sí abẹ́ ìyẹ́ àwọn kérúbù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 5

Wo 2 Kíróníkà 5:7 ni o tọ