Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 35:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pẹ̀lú Koníà àti pẹ̀lú Ṣémíà àti Nàtaníẹ́lì, àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àti Haṣabíà, Jélíélì àti Joábádì olórí àwọn ọmọ Léfì, ó sì pèsè ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ẹbọ ìrékọjá (500) àti ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n orí ẹran ọ̀sìn fún àwọn ọmọ Léfì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 35

Wo 2 Kíróníkà 35:9 ni o tọ