Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 35:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósíà sì pàṣẹ fún gbogbo àwọn ènìyàn tí ó dùbúlẹ̀ tí ó wà níbẹ̀ iye rẹ̀ ẹgbàámẹ́ẹ̀dógún ọ̀dọ́ àgùntàn àti ọmọ ewurẹ́ fún ẹbọ ìrékọjá, àti pẹ̀lú ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n akọ màlúù (3,000) gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ohun ìní láti ọ̀dọ̀ ọba.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 35

Wo 2 Kíróníkà 35:7 ni o tọ