Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 35:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jeremáyà sì pohùn réré ẹkún fún Jósíà, gbogbo àwọn akọrin ọkùnrin àti gbogbo àwọn akọrin obìnrin sì ń sọ ti Jósíà nínú orin ẹkún wọn títí di òní. Èyí sì di àṣà ní Jérúsálẹ́mù, a sì kọọ́ sínú àwọn orin ẹkún.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 35

Wo 2 Kíróníkà 35:25 ni o tọ