Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 35:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósíà, bí ó ti wù kí ó rí, ẹni tí kò yípadà kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, ṣùgbọ́n ó pa ara rẹ̀ dà kí ó le báa jà, kí ó ṣe gẹ́gẹ́ bí òfin Ọlọ́run ṣùgbọ́n ó lọ láti jà lórí àfonífojì Mégídò.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 35

Wo 2 Kíróníkà 35:22 ni o tọ