Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 35:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni àsìkò náà gbogbo àwọn ìsìn Olúwa ni wọ́n gbé jáde fún iṣẹ́ ìrántí àjọ ìrékọjá àti láti rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ọba Jósíà ti paá lásẹ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 35

Wo 2 Kíróníkà 35:16 ni o tọ