Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 34:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lábẹ́ àpẹẹrẹ àwọn pẹpẹ Bálímù ni a yí lulẹ̀, ó sì fọ́ àwọn ère sí wẹ́wẹ́, ó run àwọn pẹpẹ tí ó wà lórí rẹ̀, wọ́n sì fọ́ túútúú àti àwọn ère dídá, àwọn òrìṣà àti ère dídá. Èyí tí ó fọ́ wọn sì lùúlùú, ó sì gbọ̀n wọ́n sí orí ìsà òkú àti àwọn tí ó ń rúbọ sí wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:4 ni o tọ