Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 33:22-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Ó ṣe búburú ní ojú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí baba a rẹ̀ Mánásè ti ṣe. Ámónì sìn ó sì rú ẹbọ sí àwọn òrìṣà tí Mánásè ti ṣe.

23. Ṣùgbọ́n kì í ṣe bí i baba a rẹ̀ Mánásè. Kò rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ níwájú Olúwa: Ẹ̀bi Ámónì ń ga sí i.

24. Àwọn onísẹ́ Ámónì dìtẹ̀ síi. Wọ́n sì pa á ní ààfin rẹ̀

25. Nígbà náà, gbogbo àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà pa gbogbo àwọn tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Ámónì, wọ́n sì mú Jósíà ọmọ rẹ̀ jọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33