Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 33:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà, gbogbo àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà pa gbogbo àwọn tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Ámónì, wọ́n sì mú Jósíà ọmọ rẹ̀ jọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33

Wo 2 Kíróníkà 33:25 ni o tọ