Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 32:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀pọ̀ ogun ọkùnrin péjọ, wọ́n sì dí gbogbo àwọn orísun àti àwọn omi tó ń ṣàn tí ó ń sàn gba ti ilẹ̀ naà. “Kí ni ó dé tí àwọn ọba Ásíríà fi wá tí wọ́n sì rí ọ̀pọ̀ omi?” Wọ́n wí.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 32

Wo 2 Kíróníkà 32:4 ni o tọ