Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 32:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo iṣẹ́ yòókù ti ìjọba Heṣekíà àti àwọn ìṣe rẹ̀, ìfarajì rẹ̀ ni a kọ sínú ìwé ìran wòlíì Àìṣáyà ọmọ Ámósì nínú ìwé àwọn ọba Júdà àti Ìsírẹ́lì

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 32

Wo 2 Kíróníkà 32:32 ni o tọ