Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 32:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba pẹ̀lú sì kọ àwọn ìwé ní bíbú Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì àti ní sísọ èyí ní ìlòdì sí: “Ní gẹ́gẹ́ bí àwọn ọlọ́run àwọn ènìyàn ilẹ̀ mìíràn kò ṣe gba àwọn ènìyàn wọn kúrò lọ́wọ́ mi, Bẹ́ẹ̀ ni Ọlọ́run Heṣekáyà kì yóò gba àwọn ènìyàn rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ mi.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 32

Wo 2 Kíróníkà 32:17 ni o tọ