Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 31:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n fi gbogbo àwọn ọmọ kékèké sí i, àwọn ìyàwó, àti àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin gbogbo ará ìlu. Tí a kọ lẹ́sẹsẹ sínú ìtàn ìdílé yìí ti baba ńlá wọn fún ìrántí. Nítorí tí wọ́n ṣe òtítọ́ ní yíya ara wọn sí ọ̀tọ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:18 ni o tọ