Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 31:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àfikún, wọ́n pín sí àwọn ọkùnrin àgbà ọdún mẹ́ta tàbi ọ̀pọ̀ tí orúkọ wọn wà nínu ìtàn ìdíle láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn. Gbogbo àwọn ti yóò wọ ilé Olúwa láti ṣe oríṣìí iṣẹ́ ti a gbàwọ́n fún gẹ́gẹ́ bí ìgbẹ́kẹ̀lé wọn àti ìpín wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:16 ni o tọ