Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 31:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sádókù sì dáhùn pé “Ní ìwọ̀n ìgbà tí àwọn ènìyàn ti bẹ̀rẹ̀ sí ní mú ìdáwó wọn wá sí ilé Olúwa àti ní èyí tí yóò tó jẹ àti ọ̀pọ̀ láti tọ́jú pamọ́ nítorí Olúwa ti bùkún àwọn ènìyàn rẹ̀, ó sì sẹ́kù lọ́pọ̀lọpọ̀.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:10 ni o tọ