Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe ẹ̀wọ̀n tí a hun wọ inú ara wọn, ó gbé wọn ká orí òpó náà. Ó ṣe ọgọ́rin Pomígíránátìo (orúkọ èso igi) ó sì so wọ́n mọ́ àwọn ẹ̀wọ̀n náà

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 3

Wo 2 Kíróníkà 3:16 ni o tọ