Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 29:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ìbínú Olúwa ti ru sókè wá sórí Júdà àti Jérúsálẹ́mù ó sì ti fi wọ́n ṣe ohun èlò fún wàhálà, àti ìyanu àti ẹ̀sín, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fi ojú rẹ̀ rí i.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:8 ni o tọ