Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 29:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí pé, “Ẹ gbọ́ tèmi, ẹ̀yin ọmọ Léfì! Ẹ ya ara yín sí mímọ́ nísinsin yìí kí ẹ sì ya ile Olúwa Ọlọ́run sí mímọ́, kí ẹ sì kó ohun àìmọ́ bàbá jáde kúrò ní ibi mímọ́.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:5 ni o tọ