Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 29:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì ṣe ìparí ẹbo rírú, ọba àti gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ tẹ ara wọn ba, wọ́n sì sìn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:29 ni o tọ