Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 29:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn àlùfáà wọn sì pa Òbúkọ, wọ́n sì gbé ẹ̀jẹ̀ kalẹ̀ lórí pẹpẹ fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ láti ṣe ètùtù fún gbogbo Ísírẹ́lì, nítorí ọba ti pàsẹ kí a ṣe ẹbọ sísun àti ẹbọ ẹṣẹ fún gbogbo Íṣírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:24 ni o tọ