Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 29:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nigbà tí wọ́n sì ti kó ara wọn jọ pọ̀ pẹ̀lú àwọn arákùnrin wọn, wọ́n sì ya ara wọn sí mímọ́, wọ́n sì lọ láti gbá ile Olúwa mọ́, gẹ́gẹ́ bí ọba ti paáláṣẹ, ẹ tẹ̀lé ọ̀rọ̀ Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:15 ni o tọ