Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 28:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kan Pékà, ọmọ Remalíà, pa ọ̀kẹ́ mẹ́fà àwọn ọmọ ogun ní Júdà nítorí Júdà ti kọ Olúwa Ọlọ́run bàbá wọn sílẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 28

Wo 2 Kíróníkà 28:6 ni o tọ