Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 25:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámásíà sì bi ènìyàn Ọlọ́run pé, “Ọgọ́rùnún tálẹ́ntì tí mo ti san fún àwọn ọ̀wọ́-ogun àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń kọ́?”Ènìyàn Ọlọ́run dáhùn pé “Olúwa lè fún ọ ní èyí tí ó ju ìyẹn lọ.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:9 ni o tọ