Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 23:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú pẹ̀lú rẹ̀ àwọn alákóso ọrọrún, Àwọn eni-ọlá, àwọn olórí àwọn ènìyàn àti gbogbo àwọn Ènìyàn ilẹ̀ náà. Ó sì mú ọba sọ̀kalẹ̀ wá láti ilé Olúwa. Wọ́n lọ sínú Ààfin láti ẹnu òde tòkè. Wọ́n sì fi ọba jókoó lórí ìtẹ́.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 23

Wo 2 Kíróníkà 23:20 ni o tọ