Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 23:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo Àwọn ènìyàn lọ sí ilé Báálì, wọ́n sì fà á ya lulẹ̀. Wọ́n fọ́ àwọn pẹpẹ àti àwọn òrìṣà, wọ́n sì pa Mátanì àlùfaà Báálì níwáju àwọn pẹpẹ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 23

Wo 2 Kíróníkà 23:17 ni o tọ