Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 23:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhóiádà àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mú ọmọkùnrin ọba jáde wá wọ́n sì gbé adé sórí rẹ̀; Wọ́n mú ẹ̀dà májẹ̀mú kan fún un. Wọ́n sì kéde rẹ̀ lọ́ba. Wọ́n fi àmì òróró yàn án, wọ́n sì kígbe pé, “Kí ọba kí ó pẹ́!”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 23

Wo 2 Kíróníkà 23:11 ni o tọ