Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 22:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Jehóṣẹ́bà ọmọbìnrin ọba Jéhórámù mú Jóásì, ọmọkùnrin Áhásáyà ó sì jíi gbé lọ kúrò láàrin àwọn ọmọ-obìrin ọba, àwọn tí ó kù díẹ̀ kí wọn pa. Wọn gbé òun àti olùtọ́jú rẹ̀ sínú ìyẹ̀wù. Nítorí Jèhóṣebà ọmọbìnrin ọba Jehórámì àti ìyàwó àlùfáà Jéhóiádà jẹ́ arábìnrin Áhásáyà. Ó fi ọmọ naà pamọ́ kúrò fún Ataláyà, kí ó má ba à pa á.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 22

Wo 2 Kíróníkà 22:11 ni o tọ