Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 22:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Ataláyà ìyá Áhásáyà ríi wí pé ọmọkùnrin rẹ̀ ti kú, ó tẹ̀ṣíwájú láti pa gbogbo ìdílé ọba ti ilẹ̀ Júdà run.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 22

Wo 2 Kíróníkà 22:10 ni o tọ