Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 21:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n dojú ìjà kọ Júdà, wọ́n gbàá, wọ́n sì kó gbogbo ọrọ̀ tí a rí ní ilé ọba pẹ̀lú, àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ àti àwọn ọmọkùnrin kankan kò kù sílẹ̀ fún un bí kò ṣe Áhásáyà, tí ó kéré jùlọ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 21

Wo 2 Kíróníkà 21:17 ni o tọ