Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 20:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù wọ́n jáde lọ sí ihà Tékòa. Gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ń jáde lọ, Jéhóṣáfátì dìde dúró ó sì wí pé, “Ẹgbọ́ mi, Júdà àti ènìyàn Jérúsálẹ́mù! Ẹ ní ìgbàgbọ́ ninú Olúwa Ọlọ́run yín ẹ̀yin yóò sì borí, ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú àwọn wòlíì rẹ̀ ẹ̀yìn yóò sì ṣe rere.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:20 ni o tọ