Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 20:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà díẹ̀ lára àwọn ọmọ Léfì àti àwọn ọmọ Kóhátì àti àwọn kórì sì dìde dúró wọ́n sì sin Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, pẹ̀lú ohùn ariwo ńlá.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 20

Wo 2 Kíróníkà 20:19 ni o tọ