Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsin yìí, èmi n kọ́ ilé kan fún orúkọ Olúwa Ọlọ́run mi àti láti yà á sí mímọ́ fún un àti láti sun tùràrí olóòórùn dídùn níwájú rẹ̀, fún gbígbé àkàrà-ìfihàn ìgbàkúgbà, àti fún síse ẹbọ sísun ní gbogbo àárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́ àti ní ọjọọjọ́ ìsinmi àti òṣùpá tuntun àti ní àpèjọ Olúwa Ọlọ́run wa. Èyí ni àsẹ fún Ísírẹ́lì láéláé.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 2

Wo 2 Kíróníkà 2:4 ni o tọ