Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì rán iṣẹ́ yìí sí Hírámíà ọba Tírè:“Rán àwọn igi kédárì sí mi gẹ́gẹ́ bí o ti ṣe fún baba à mi Dáfídì. Nígbà tí ó fi igi kédárì ránsẹ́ sí i láti kọ́ ààfin tí ó ń gbé.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 2

Wo 2 Kíróníkà 2:3 ni o tọ