Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa yóò sì gé gbogbo àwọn ìtí igi láti Lébanónì tí ìwọ yóò lò pẹ̀lú a ó gbé wọn fò lójú omi òkun lọ sí Jópà. Lẹ́yìn náà ìwọ lè kó wọn gòkè lọ sí Jérúsálẹ́mù.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 2

Wo 2 Kíróníkà 2:16 ni o tọ