Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 18:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ pípẹ́, ìjà náà sì ń pọ̀ síi, ọba Ísírẹ́lì dúró nínú kẹ̀kẹ́ rẹ̀ kọjú sí àwọn ará Síríà títí ó fi di àsaálẹ́. Lẹ́yìn náà ní àkókò ìwọ oòrùn, ó sì kú.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:34 ni o tọ