Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 18:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhábù ọba Ísírẹ́lì sì béèrè lọ́wọ́ ọba Jèhóṣáfátì, ọba Júdà pé, “Ṣé ìwọ yóò lọ pẹ̀lú mi sí Rámótì Gílíádì?”Jehóṣáfátì sì dá a lóhùn pé, “Èmi wà gẹ́gẹ́ bí mo ti ṣe wà, àti àwọn ènìyàn mi gẹ́gẹ́ bí ènìyàn rẹ àwa yóò pẹ̀lú rẹ ninú ogun naà”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:3 ni o tọ