Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 18:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìránsẹ́ tí ó ti lọ pe Míkáyà sì wí fún un pé, “Ẹ wò ó, gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin kan àti òmíràn wòlíì fi ẹnu kan sọ rere fún ọba. Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ kí ó níí ṣe pẹ̀lú ti wa, kí o sì sọ rere.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:12 ni o tọ