Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 16:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Ásà mú wúrà àti fàdákà jáde ninú ilé ìsúra ilé Olúwa àti ààfin ọba ó sì ránsẹ́ sí Bẹni-Hádádì ọba Árámù, ẹni tí ń gbé ní Dámásíkù, ó wí pé,

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 16

Wo 2 Kíróníkà 16:2 ni o tọ