Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kẹrìndínlógójì ìjọba Ásà, Básà ọba Ísírẹ́lì gòkè wá sí Júdà ó sì kọlu Rámà, láti ma bàá jẹ́ kí ẹnikẹ́ni lè jáde tàbí wọlé tọ Ásà ọba Júdà lọ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 16

Wo 2 Kíróníkà 16:1 ni o tọ