Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 14:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n pa gbogbo àwọn ìletò tí ó wà ní ẹ̀bá Gérárì, nítorí tí ìpayà Olúwa ti sọ̀kalẹ̀ sórí wọn. Wọ́n kó gbogbo ìkógún àwọn ìletò yìí lọ, níwọ̀n ìgbà tí ọ̀pọ̀ ìkógun ti wà níbẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 14

Wo 2 Kíróníkà 14:14 ni o tọ