Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 14:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ásà àti àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ sá tẹ̀lé wọn ní jìnnà réré sí Gérárì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀, àwọn ará Kúṣì ṣubú, wọn kò sì le sán padà mọ́. A fún wọn pa níwájú Olúwa àti ọmọ ogun rẹ̀. Àwọn ọkùnrin Júdà kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkógún.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 14

Wo 2 Kíróníkà 14:13 ni o tọ