Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 12:15-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Fún tí iṣẹ́ ìjọba Réhóbóámù láti ìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìrantí ti Ṣémáíà wòlíì àti ti Idò, aríran tí ó ní ṣe pẹ̀lú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ àwọn baba ńlá? Ìtẹ̀ṣíwájú ogun jíjà sì wà láàárin Réhóbóámù àti Jéróbóámù.

16. Réhóbóámù sinmi sínú ìlú ńlá ti Dáfídì. Ábíjà ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 12