Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 12:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún tí iṣẹ́ ìjọba Réhóbóámù láti ìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìrantí ti Ṣémáíà wòlíì àti ti Idò, aríran tí ó ní ṣe pẹ̀lú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ àwọn baba ńlá? Ìtẹ̀ṣíwájú ogun jíjà sì wà láàárin Réhóbóámù àti Jéróbóámù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 12

Wo 2 Kíróníkà 12:15 ni o tọ