Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 12:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Réhóbóámù fi ara rẹ̀ lélẹ̀ gidigidi ní Jérúsálẹ́mù, ó sì tẹ̀ ṣíwájú gẹ́gẹ́ bí ọba. Ó jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlélógójì nígbà tí ó di ọba. Ó sì jọba fún ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ní Jérúsálẹ́mù, ìlú ńlá tí Olúwa ti yàn jáde kúrò nínú gbogbo àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì ní èyí tí ó fẹ́ fi orúkọ rẹ̀ sí.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 12

Wo 2 Kíróníkà 12:13 ni o tọ