Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 12:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítori ti Réhóbóámù rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, ìbínú Olúwa yí padà kúrò lórí rẹ̀, a kò sì paárun pátapáta. Nítòótọ́, ire díẹ̀ wà ní Júdà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 12

Wo 2 Kíróníkà 12:12 ni o tọ