Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 11:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó hùwà ọlọ́gbọ́n, nípa fí fọ́nká díẹ̀ nínú àwọn ọmọ rẹ̀ jákè jádò ká àwọn agbégbé Júdà àti Bẹ́ńjámínì àti sí gbogbo àwọn ìlú ńlá aláàbò. Ó fún wọn ní ọ̀pọ̀ ohun tí wọ́n fẹ́, ó sì gba ọ̀pọ̀ ìyàwó fún wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 11

Wo 2 Kíróníkà 11:23 ni o tọ