Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsinyìí Olúwa Ọlọ́run, jẹ́ kí ìlérí rẹ sí baba à mi Dáfídì di mímúsẹ, nítorí ìwọ ti fi mí jẹ ọba lóri àwọn ènìyàn tí ó pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:9 ni o tọ