Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún mi ní ọgbọ́n àti ìmọ̀, kí èmi kí ó lè tọ́ àwọn ènìyàn wọ̀nyí sọ́nà, nítorí ta ni ó le è ṣàkóso àwọn ènìyàn rẹ tí ó pọ̀ yanturu wọ̀nyí?”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:10 ni o tọ