Nígbà tí àpótí ẹ̀rí májẹ̀mú Olúwa wá sí ibùdó, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì dìde láti kígbe tó bẹ́ẹ̀ tí ilẹ̀ sì mì tìtì.