Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ti ń kú lọ, obìnrin tí ó dúró tì í wí pé, “má ṣe bẹ̀rù; nítorí o ti bí ọmọ ọkùnrin.” Ṣùgbọ́n kò sọ̀rọ̀ tàbí kọ ibi ara sí i.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 4

Wo 1 Sámúẹ́lì 4:20 ni o tọ